3- Ó tún fi Ẹni tí Ó dá akọ àti abo búra. [998] Allāhu Ẹlẹ́dàá ni Ẹni tí Ó dá akọ àti abo. Ó sì ń fi ara Rẹ̀ búra.